Oni iyawo ogota, ninou awon obinrin to lèwa gan Ati okpolokpo, ati okpolokpo Ma gbagbé awon ogori alè, tè nin Ati gbogbo awon tara ijoba rè Ati okpolokpo, Makeda, Makeda, Makeda
Ti won ni ikoko ifè foun yin Shugbon, lale yi mori ninu oju yin Ati okpolokpo, ati okpolokpo Kpé okan obinrin kan lo n´da yin l´odju ! Ati okpolokpo , Makeda Makeda, Makeda Eh !
Kini n´kan, ta m´kpé nin imi Kossi, ko djè ifé Kini n´kan, ta m´kpé nin emi Kossi, ko lè djè ifé Eyi ti o tu kpalè kpelou agara a Okan ènin ti o ni sokan Kini^n´kan, ta m´kpé nin emi Kossi, ko lè djè ifé Ko lè djè ifé
Elo dja yé yin, kpèlou igbadun kpikpo, kpikpo Makeda ati okpolokpo, ati okpolokpo Ti eniyan ko le foju mon Ati okpolokpo okan ibanuje Ati okpolokpo, Makeda
Ti won ni ikoko ifè foun yin Shugbon, lale yi mori ninu oju yin Ati okpolokpo, ati okpolokpo Kpé okan obinrin kan lo n´da yin l´odju ! Ati okpolokpo , Makeda
Nin sinko èwa kodju mon min Nin sinko èwa kodju mon min Lesso m´kpé omi ti mon moun Omi aafin rè, Emin mon ji nin Kini n´kan, ta m´kpé nin imi « Ife ti mou ni foun e ni, Makeda »
Kini n´kan, ta m´kpé nin èmi « Ife ti mou ni foun e ni, Makeda »
Kini n´kan, ta m´kpé nin imi Kossi, ko djè ifé Kini n´kan, ta m´kpé nin emi Kossi, ko lè djè ifé Eyi ti o tu kpalè kpelou agara a Okan ènin ti o ni sokan
Kini n´kan, ta m´kpé nin imi Kossi, ko djè ifé Kini n´kan, ta m´kpé nin emi Kossi, ko lè djè ifé Eyi ti o tu kpalè kpelou agara a Okan ènin ti o ni sokan
Kini n´kan, ta m´kpé nin imi
Kossi, ko djè ifé Kini n´kan, ta m´kpé nin emi Kossi, ko lè djè ifé Eyi ti o tu kpalè kpelou agara a Okan ènin ti o ni sokan