Méjé, mèsan, méji, ọkan, méjé, duro Méjé, mèsan, méji, ọkan, mèsan bèrè Méjé, mèsan, méji, ọkan, méjèji won foun oti Shugbon ọkan lo moun ti
« Makéda » Bayi ni baba mi Akebo man kpé min "Balqis" Ni igbami won man kpé min « Makéda » Bayi ni baba mi Akebo man kpé min "Balqis" Ni igbami won man kpé min Èmi ni Olori ti Guusu, Guusu, Guusu Emi ni Olori… Sheeba, Sheeba, Sheeba Èmi ni Olori ti Guusu, Guusu, Guusu Emi ni Olori… Sheeba, Sheeba, Sheeba !
Ti wonti so m´kpé oju mijè dudu bi éshuro Ara mi man dan bi okuta iyèbiyè dudu
Iyèbiyè dudu Ṣhugbọn kojè ki ayé té min, komanjè iya l´odjodjumon Ti obi min omon aladé Omon aladé L´akọkọ obinrin ni min
Ti wonti so m´kpè emi nin fuyè bi afèfè Ara mi ro bi ara igala Bi ara igala Shugbon ni gbogbo oshè mérin irora kan ma yangbé mi N´tori ènin èyin è fè ran mi rara È fè ran mi rara Ki lo djè m´kpè èkpé min nin ayimon?
Méjé, mèsan, méji, ọkan, méjèji won foun oti Shugbon ọkan lo moun ti "Axoum" Ni oruko ilou ti won bi mi "Méroé" Lori a mimọ èrèkusu ti Nile "Axoum" Ni oruko ilou ti won bi mi "Méroé" Lori a mimọ èrèkusu ti Nile
Èmi ni Olori ti Guusu, Guusu, Guusu Emi ni Olori… Sheeba, Sheeba, Sheeba Èmi ni Olori ti Guusu, Guusu, Guusu Emi ni Olori… Sheeba, Sheeba, Sheeba !
Ti won so m´kpé èrin mi kpashè awon sèhin Kpè guiguisè mi ni irinkérindo to dara To dara Shugbon nigbati n´wa bi ọmon mon wa jiya gan N´tori kini èsso m´kpé abuku min ni Abuku min ni Boya ti mon pèja, mon ni lati gba iya
Ti won so m´kpé awon jufu mi, adun dudu ni wo fitché Won so wi kpé awon akpo temin won koun kpelou Ara Dragoni, Ara Dragoni Titi nan nin won ko n´kpé èmin oni kpashè N´tori m´kpé obirin koni ọtoun oro sisso Oro sisso Boya ninou ikpa yara
Méjé, mèsan, méji, ọkan Méjé, duro Méjé, mèsan, méji, ọkan Mèsan bèrè Méjé, mèsan, méji, ọkan Méjèji won foun oti Shugbon ọkan lo moun ti
Mon béré yin Oba Solomoni Ta lowa lèyin ohun olusin ? Mon béré yin Oba Solomoni Ta lowa lèyin ohun olusin ?
Méjé, mèsan, méji, ọkan L´ ojo meje ni eje wa duro Méjé, mèsan, méji, ọkan Oshu kesan ni aman duro bi omon Méjé, mèsan, méji, ọkan Omou meji o n´foun ni amoun Méjé, mèsan, méji, ọkan
Omo ti oni ongbé!
"Makeda" Bẹẹni, emi nin ohun olusin "Balqis" Emi ni OBIRIN AYERAYE "Makeda" Bẹẹni, emi nin ohun olusin "Balqis" Emi ni OBIRIN AYERAYE
Èmi ni Olori ti Guusu, Guusu, Guusu Emi ni Olori… Sheeba, Sheeba, Sheeba Èmi ni Olori ti Guusu, Guusu, Guusu Emi ni Olori… Sheeba, Sheeba, Sheeba !