Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Ọmọ Dafidi, léni ti o ba djè Oba Itẹ rẹ o monlè kpélou wura Oti wa ni shọ lowo Kiniun méji Kiniun meji ti ko jéra o N´tori agbara won foun yin l´okan bale Kiniun meji ti ko jéra o Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Shugbọn ma gbagbé l´ayé, kpé ojo buruku kan owa Igbati won ji janu oruka rè Ànjọnú Sakhar lo fọ agbara rè
Ànjọnú Sakhar lo dji oro rè
Awon éyé ijosin Awon éjé korira Awon éyé ijosin Awon éjé korira Asho ti awon olowo Kpelou asho ti awon talaka mawo lo si boji
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Ọmọ Dafidi, léni ti o ba djè Oba Tabili rè nin smaragdu On simi lori ẹssẹ oniyèbiyè mẹrin
Kiniun meji ti ko jéra o To fun yin ni agbara, okanbalé Kiniun meji ti ko jéra o Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Shugbọn ma gbagbé l´ayé, kpé ojo buruku kan owa Igbati won ji janu oruka rè Ànjọnú Sakhar da yin kpada bi talaka Ànjọnú Sakhar da yin kpada bi alagbé
Awon éyé ijosin Awon éjé korira Awon éyé ijosin Awon éjé korira Asho ti awon olowo Kpelou asho ti awon talaka mawo lo si boji
Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh, Oh, Oh, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oh