Era ile, era ile Won yin baba l´oke Yanrin okun, yanrin okun Won n yin baba l´oke Eranko ile, eranko igbo Won n yin baba l´oke
Awon alaini, awon tan ti ni Won yin baba l´oke
Ko se igbati nkan ba se yan Ko to mo pe baba n be l´oke Ko se igbati nkan ba se yan Ko to mo pe looto o n be l´oke You don´t have to wait till you feel the pain You can start right now It´s not too late It´s not too late, to be grateful
Era ile, era ile Won yin baba l´oke Yanrin okun, yanrin okun Won yin baba l´oke Pe mo wa laye, mo wa laye Gbogbo n ti mo ni, ma fin yi o l´ogo
Believe this world a better place
Ko se igbati nkan ba se yan Ko to mo pe baba n be l´oke Ko se igbati nkan ba se yan Ko to mo pe looto o n be l´oke You don´t have to wait till you feel the pain You can start right now It´s not too late It´s not too late, to be grateful
Wo mi, bi mo se n f´ope ye baba Da di da dada Da di da dudu Da di da dada Da di da dudu It´s not too laaate