Accueil  đŸ’ƒđŸŽ€ Paroles de chanson Française et Internationnales

 A   B   C   D   E   F   G   H   I   J   K   L   M   N   O   P   Q   R   S   T   U   V   W   X   Y   Z   0   1   2   3   4   5   6   7   8   9 
Artiste : Ibrahim Maalouf
Titre : Ogbo
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh

Ọmọ Dafidi, lĂ©ni ti o ba djĂš Oba
Itáșč ráșč o monlĂš kpĂ©lou wura
Oti wa ni shọ lowo Kiniun mĂ©ji
Kiniun meji ti ko jéra o
NÂŽtori agbara won foun yin lÂŽokan bale
Kiniun meji ti ko jéra o
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba

Shugbọn ma gbagbĂ© lÂŽayĂ©, kpĂ© ojo buruku kan owa
Igbati won ji janu oruka rĂš
ÀnjọnĂș Sakhar lo fọ agbara rĂš

ÀnjọnĂș Sakhar lo dji oro rĂš

Awon éyé ijosin
Awon éjé korira
Awon éyé ijosin
Awon éjé korira
Asho ti awon olowo
Kpelou asho ti awon talaka mawo lo si boji

Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba

Ọmọ Dafidi, lĂ©ni ti o ba djĂš Oba
Tabili rĂš nin smaragdu
On simi lori áșčssáșč oniyĂšbiyĂš máșčrin

Kiniun meji ti ko jéra o
To fun yin ni agbara, okanbalé
Kiniun meji ti ko jéra o
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba

Shugbọn ma gbagbĂ© lÂŽayĂ©, kpĂ© ojo buruku kan owa
Igbati won ji janu oruka rĂš
ÀnjọnĂș Sakhar da yin kpada bi talaka
ÀnjọnĂș Sakhar da yin kpada bi alagbĂ©

Awon éyé ijosin
Awon éjé korira
Awon éyé ijosin
Awon éjé korira
Asho ti awon olowo
Kpelou asho ti awon talaka mawo lo si boji

Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh, Oh, Oh, Oh
Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oh